Olori lana ni naomi je ati wipe ko ko egbin kankan ba ile Yoruba, abi eko mo ohun ti e n so lenu ni, emaronu jinle keto soro, Pa Awolowo sewon, Obasanjo sewon ati bebe lo.
How is it not alright?. The greatest yoruba leader Awo went to jail. Naomi is not above the law, she has relinquished the title of olori when she divorced Ooni on Instagram. She should be charged for 3rd degree mass murder for hosting a publicized event at a venue with only one entrance for over 15000 kids
Ododo oro ni ki olorun maje ki ah se ore tadaran ko da oo ahah beru eniyan laye aye to to fun😢😢😢😢😢
Sebi naomi lope awon naa pa 3:39
Olori lana ni naomi je ati wipe ko ko egbin kankan ba ile Yoruba, abi eko mo ohun ti e n so lenu ni, emaronu jinle keto soro, Pa Awolowo sewon, Obasanjo sewon ati bebe lo.
Ki olorun oba ma je ki a shi oore se.
Se.aanu maa wopo nile yoruba mo,lati se,opo lawa to fe saanu tiwon fi dawo won duro,Ebi tani?
Otito koro,iro laye nfe,ebi awon ojelu tiwon pe rawon loselu
Hmmmmm Nigeria 🤔🤔🤔
Oro ojo ola ni nile Ife. Ti o ba je wipe won ma yan oba ile Ife akosile yio wa wipe omo ti Naomi bi fun oba, iya re se ewon ri.
Kiise ẹgbin rara nitoripe Kiise ìyàwó ọba mọ
Hmmm, abawon nla ni ki olori divorce oba lori Instagram
Ha Yoruba yo yo bi ina ale hun,won a ni,ade gun ,won a ni ko gun mo .Eru yin ma bami o.Oluwa a ko won yo.
Alaroye online you are not first to post news nows
Alaroye online you are not first to post news now